From: husseein selemani [kahingafr@yahoo.fr]
Sent:
Monday, January 01, 2007 2:23 PM
To:
rasyed@emirates.net.ae
Subject: Mirza His life at a Glance in
Yoruba/Nigeria
Ijo
Alatako Ahmadiyya ninu Esin Islam
Mirza Ghulam Qadiani
Itan
igbesi Aiye re niwonba soki
Awon
itan Arikogbon nla to sele si-i ninu Igbesi Aiye re
Lati owo Dr
Syed Rashid Ali
1839/40
Ni Mirza wa si Aiye lati
ara Chiragh Bibi ati Ghulam Murtaza.
1846
- Mirza bere si-i ko eko Al-Qur’an ati awon hadiths pelu iran lowo Molvi
Fazl Ilahi
1849
- Molvi Fazal Ahmad ko ni awon orisirisi eko
1852 /
1853
- Mirza so yigi re akoko pelu Hurmat Bibi alias Phajje di
Maan Latara yigi yi loti bimo meji,
Sultan Ahmad ati Fazal Ahmad
1857 /
58
- Gul Ali Shah ko-o ni eko awon ofin ijinle ti nwon fi nso ede Larubawa
1857
Ni ibere ija ominira ti a
mo si ote awon India
- Latile fira re han gegebi omo odo rere ti nsotito pelu olowo ori re
iyen
Ijoba British, baba Mirza bun ijoba
British ni aadota awon agesi jagun
latile fi ba awon musulumi
ja.
- Mirza Ghillare Qadir, egan Mirza ti-i se akobi baba Mirza
eniti o je ikan ninu Akogun ipin
kerindilaadota labe ogagun
Nicholson, pa pupo ninu awon omo ogun
Islam fun ominira legbe
Sialkot.
1864
- Mirza sa kuro nile baba re lehin igbati o gba owo isimi lenu ise ti
baba
re tosi na ni inakuna, ina
apa.
1864-68
- Mirza dari ipo akowe agba ni ile ejo Sialkot
- Mirza losi idanuwo awon amofin nibi toti fidi
remi.
- Mirza yan Alfa ijo khrist kan ni ore ayo, eiti o gbe nkan pataki se
lehin
naa
1868
- Ijoba England yan igbimo kan lati rori si awon ona ti nwon yio gba lati
yo emi ijagu soju ona Olohun Kuro lokan
awo musulumi
- Mirza fi ipo akowe agba sile o fi wa si Qadian
- O firare han gegebi oniwasi iberu ati ipaya
Olohun
1870
- Ababo
ijoko igbimo oba fun awon agbenuso ijoba Briish re : « A
laye
lori bi ijoba Britain
se de ilu India »
Abajade igbimo naa nso wipe ki nwon o
yan iranse Apostolique kan ki
o le pa emi jihad re kuro lokan awo
musulumi.
1871
- Mirza Ghulan ni nwon yan sipo iranse Apostolique
naa
1877
- Awon alase ipo yi fi esun odaran arufin kan
Mirza
1879
- Mirza Ghulan perare ni ayanfe Olohun eniti Olohun ran nise si
gbogbo mutumuwa latile salaye ododo Esin
Islam fun won
1
- Mirza Ghulam kede wipe owon yio pin iwe « Braheen-e-
Ahmadiyya » ka
kiri, iwe ti owo yi o te ni aadota ipele.
-
Mirza Ghulam kede tora iranlowo owo, osi gba awon agbatele latile fi gbe
Braheen-e-Ahmadiyya jade.
1879-84
- Mirza Ghulam pin ipele merin ninu iwe « Braheen-e-
Ahmadiyya »
ka kiri
1884
- Mirza
Ghulam da iwe « Braheen-e-Ahmadiyya » duro ni
kiko.
-
Laarin odun marundilogbon Mirza Ghulam te iwe bi ogorin
-
Mirza npe iwe re « Braheen-e-Ahmadiyya » ni isipaya abi iwe ti Olohun fi
ranse si awon eru re
-
Mirza Ghulam nperare ni oniwasu ipaya Olohun lododo (Mujaddid dine)
oluso esin dotun
-
Mirza Ghulam so yigi re keji pelu Shah jehan Bergum, omobirin Nasir Nawal,
eniti o bimo meta fun-un awon
naare
1-
Mirza
Bashiruddin Mehmood (Arode keji to si tun je baba Tahir, Arole to wa lori oye
nississinyi)
2- Mirza Bashir
Ahmad (eniti o ko iwe Seeratul-Mahdi)
3-
Mirza Sharif
Ahmad
- Nigbati
Mirza Ghulam fi nso yigi keji o jewo loju gbogbo eniyan wipe oko
towun ko sise mo
O sadura wipe Olohun fun isa oko tuwun
lokun kole ma gbe
O so wipe Olohun fi isipaya kan fi rase
si owun ki owun Sewe kan ti yio je ara
tuwun ma
gbe
- Latara
awon ilana ti Olohun juwe fun-un, o sewe ale kan ti
npeni « TIRYAQ-e-ILAHI » eyiti
ewe pataki towa ninu re nigbo
ninu
(OPIUM)
- Mirza
Ghulam toro lodo awon eniyan wipe ki nwon o bura wipe awon gba
owun gbo ni
ojise
-
Mirza Ghulam ntoro peki Mohamadi Begun ran owun lowo lati so yigi keta
ohun to npeni isipya lati odo Olohun ati
pe gbogbo eyito wun ko je niu isoro ti
yio fe kodi towun lati fe omobirin yi
yio ko igbesi Aiye mobiri naa ati enito ba
fee sinu idatmu ati
ifunpinpin
1888
- Mirza
Ghulam so setigbo eniyan wipe : « Kosi ona imole kan fun awon
eniyan lati mo ododo towun
yato si iro towun bi ki-i ba se ona iranse ati
isipaya towun angan » (Ana-e-e
Kamalate Islam, Roohani khazain ipele
Karun oju ewe 288 lati owo Mirza
Ghulam)
-
Mirza Ghulam ko ipahinkeke inira ba akofe iyawo re ati awon omo re nitori ki
nwon le ra-an lowo lati fe Bergum atipe
bi nwon ko ba lowo si-i Begum koni
se fe fun-un-
2
1891
- Mirza Ghulam nperare ni Messiah, o si npe Messiah toto niro O npe
awon ti nwon jaro re ni
opuro
-
Mirza Ghulam nperare ni Mariam
- Mirza
Ghulam tun nperare ni emi mimo ti Angel fe si Mariam lara to fi
loyun
-
Mirza Ghulam nperare ni Issa (Jesus) lehin igbati o se osu mewa ninu
ara re, nigbati o je wipe owun nikan naa
ni nperare ni Mariam lo tun
perare ni Issa
(Jesus)
O so bayi wipe : « Bayi ni emi
di Jesus omo Mariam » (Kishtee Nooh, Roohai
Khazain ewo oju ewe 87 si
89)
1891
- O da ijo Ahmadiyya sile ninu Esin Islam
- Mohammadi Begum so yigi pelu Mirza Sultan Baig
1892
- Ni isotan, lakotan
- Mirza ko akofe iyawo re sile
- Mirza ko omo re keji sile, o fi ogun du-u Akiyesi pataki : Akofe iyawo re je
ebi Mohammadi
Begun
1893
- Abdullah
khan Atham, alfa ijo Khrist kan lo pe Mirza ni ipade iforo jomitoro
oro kan lori alaye ododo Esin Islam
- Mirza so bayi : « Gbogbo awon eiyan ni nwon gbamigbo pelu
awon oro mi
yato si awo omo pansaga ti Olohun ti di
okan nwon » (Aina-e- kamalate
Islam, Roohani Khazain vol. R ;
548) E gbayi yewo : Awo akobi omo re ti
Mirza Ghulam so yigi iya nwon ti nje
akofe iyawo re, awon omo ke ko gba
baba nwon Mirza Ghulam ni
Messia !
Féb-1893
- O bere si ni se ipolongo iforo jomitoro oro ti yio waye laari owu ati
Atham
-
Ete Abuku ati itiju to ga i Mirza Ghulam ri he ninu iforo jomitoro oro yi
ohun to fa kuro ninu Esin Islam pupo
awon musulumi ti igbagbo won le.
22/5-5/6/1893
- A lako igba Mirza Ghulam tun kede wipe emi Olohun nso fun owun wipe
Atham yio hu ni 5 September
1894
O so bayi : « Ti isipaya ti
Olohun fi ran mi yi ba jasi iro, faramo gbogbo ibawi
to ba tibe jade » mo gbodo di eni
abuku, ki ateju mi dudu, ki nwo pami ni pipa
enito pokunso ku… Mo bura wipe Olohun
yio se gbogbo ohun ti mo wi yen
lakotan pata pata Ile ati sama le ma yi
sugbon oro Olohun ki-i yipada (Jang-
e-Muqqadas, Roohani Khazain vol 6 P.
293)
Avr
1894
- Atham tun nsemi laye pelu alafia lehin 5 september 1894, ohun to yapa
si
isipaya ati iriran Mirza Ghulam Pupo pa
Atham nipakupa, awo eni aïmo ni
nwon fara kasa
re.
4/09/1896
- Ota rire : Mirza se awon epe kan sori awon omo erupe ti o bu o si
dawon
sinu koto nla kan ko le jasi isoro nla
ti yio fa iku Atham.
3
6/09/1894
- Awon elesin Khrist nsajoyo odun isegun ti Alfa nwon Abdullah. Atham segun
Mirza Ghulam, nwon si fi Islam se yeye
leiti nsowipe awon ki Mirza ku orire,
awon gboriyin fun-un. Sibe-sibe Mirza
tun nfese isipaya ati iriran re mule lori
iku Atham ati isoyigi Mohammadi Begum O
nwipe : « Toba je wipe iro ni mo
pa, ki nku lojiji ki isipaya ati iriran
ma se ri bee » (Anjame Atham)
1896
- O sekede
isipaya yi : « Nwon si nbere bayi wipe toba jododo so wipe :
« Beei, mo foruko Olohun bura ododo
ni, ti e kosi le di-i lati
sele. Awa ni a so
yigi re fun-un-kosi eni to le yi oro mi
pada » (Asmani
Faisala)
27/07/1896
- Mirza Ghulam pa adapa iro mo awon iya baba ati iya Jesus wipe onisina
alagbere ni nwon je, atipe ninu eje nwon
ni owun ti jogun re, nidi eyi lowun fi
faramo awo oni
pansaga.
-
Mirza Ghulam kowe ebe si ijoba Britain.
-
Mirza Ghulam fi ebun ranse si obabirin Victoria nigbati nuruge ade
owo (fadaka)
1897
- Awon ile ise owo-ode fi esun arufin kan Mirza
-
Awon fura si-i wipe o lowo inu iku Pandit Lekharam, awon iwe ejo kan
ti sile fun-un ati idalare
re
-
Mirza ko iwe ebe si igbakeji olori orilede Punjab to fi nsalaye fun-un
abi ran-an leti wipe :
-
Eru, omodo to sotito pelu awon oba nwo ni awon baba baba Mirza
Ghulam je
-
Atipe owu gangan Mirza omo odo awon Britain ni owun je
1898
- Latigba ewe re titi to fi di omo odun marun
1899
- dilaadorin
ni Mirza Ghulam ti pinu lori atima fi gege ikowe re ati ahan
re yi awo musumuli lokan pada kuro loju
ona inigbagbo ododo si
Olohun lo sibi ima ki ife awon English
siwon lokan pelu ima emi jihad
kuro lokan awon asiwere
musulumi
- Nwon fi esun odara kan-an nitoripe o te ofin ijoba
mobe
1900
- Mirza pa ofin ijagun seju ona Olohun (Jihad) re
- Mirza pe awon omo ijo Ahmadiyya pawon lase pe ki nwon o ma
pe owun ni ojise nigbati ijoba nkaye
awon eniyan ti nwon ngbelu
-
Mirza nperare ni ojise
25/05/1900
- Mirza Ghulam kede wipe gbogbo awon ti ko gbawun ni ojise nwon
ntapa si ofin Olohun ati t’ojise Nidi
eyi ina nibudesi nwon.
1901
- Ife Mohammadi Begum ku lokan Mirza tobee to fi nsala la. O tun gbe
ikede tuntu miran jade latile
gbona ete miran tun irin re gbe, ona ti
Begum ko fi nile bo lowo re ni
fife nitoripe awon ibere kan ti o to
telerawon lati odo Olohun wa
ni.
4
1902
- Nigbehin, awon apakan musulumi mu ero kan jade latile fi fun
Mohammadi Begum nifokanbale. Jaafer
Zitly lo kede sinu iwe iroyin
kan wipe : « Owun ri-i ninu
ala towun wipe iyawo Mirza Ghulam di
iyawo towun ». Oro pesi je lenu
Mirza, agara da-a tenu-tenu. Owa
dake bi oyaya ko so gbolohun kankan sori
oro yi to fi ku ni odun 1908.
Mohammadi Begum gbele aiye pelu okore
fun ogoji odun lehin iku
Mirza pelu alafia ati opolopo
ore.
8 Nov
1902 - Mirza
kede wipe : « Awon ito ka awon oro towun ki-i-se awon Hadiths
bikose awon
Ayaths Al-Qur’an ati awo isipaya towun gangan, lafikun,
nigbamiran mo ma nka awo Hadiths ti ko
ba tako awo isipaya mi
Eyitoku inu awon Hadiths, mo ma ndawon
nu bi iwe tori » (Zamima
Nuzoole Maseeh, Rhoohani Khazain vol 19
P. 140)
1903
- Mirza ko
Minarat-u-l-Maseeh silu Qadian, lehin odu mejila to
fi polongo arare ni Messia ti nwon
nwi
1904
- Mirza nperare ni Khrishna Olohun awon Hundous
1905
- Mirza fi ami soju awon ala ite ti Olohun bukan, yonusi nilu
Qadian.
1906
- Mirza jewo
wipe arun opolo nda owu laanu, atogbe si nyo-o lenu
tobee to fi nto nigba ogorun lojumo kan,
latigba toti perare ni Ayanfe
Olohun ti o ran nise ni odun
1879.
- Mirza gberare sepe niwaju Olohun laarin owun ati sepe yi sinu awon
iwe iroyin leiti nso bayi wipe ki Olohun
Alagbara julo ki o pa opuro
ninu awon mejeji nigbati olododo yio
semi lo pelu alafia ati opolopo
ore. Arun igbe yiya ati ebi abi aru
ajakale i kio pa opuro laarin awon
mejeji nitoripe awon arun mejeji yi
ntumo si ibawi Olohun fun eni to ba
ku iku nwon.
1907
- Mirza puro wipe Olohun pe owun ni Muhammad ati Ahmad, odun
merindilogbon ti rekoja lori re ninu iwe
Braheen-e-Ahmadiyya
(Haqeeqatul-Wahi, Roohani
Khazain vol 22 P. 502)
- Mirza Ghulam npa adapa iro wipe Olohun fun owun ni 300.000 ami
latifi jeri awon isipaya
towun.
15 Mai
1907
- Mirza fan enu, sete leso wipe awon ayath Al-Qur’an ti Olohun sokale
latifi sapole Annabi Muhammad (SAW), tun
sokele leekasi latifi sapole
owun Mirza naa
a-
ese 7 ori
17
b-
ese 55 ori
1
c-
ese 9 ori
33
d-
ese 53 ori
9
e-
ese 17 ori
1
f-
ese 3 ori 31
g-
ese 48 ori
1
5
h-
ese 73 ori
15
i-
ese 73 ori
1
j-
ese 107 ori
3
k-
ese 36 ori
3
(Haqeeqat-u-l
Wahi Roohani Khazain vol 22)
- Mirza nsoro enu ni dun wipe : Olohun ndaruko towun lehin oruko
gbogbo ojise kookan, o wipe :
« owun ni Adam, owun ni Noe, owun
ni Abraham, owun ni
Isaac, owu ni Jacob, owun ni David, owun ni
Issa omo Mariam, owun ni Mohammad (ki ike
Olohun ma lo bawon)
Odun
1907 :
Mirza pin ipele kaarun ninu
iwe « Braheen-e-Ahmadiyya ka kiri.
Ninu awon oro itisiwaju to wa ninu abala
iwe naa nipe : « Ni ipilese,
mo sadewun wipe ipele aadota ni maa fi
ko-o. Sugbon nigbati owun
pa odo ti a fi kun marun to fi nje
aadota ninu akosile re, oseku
marun,
Mirza wipe emi ti mu adewun mi se
pelukiko ipele karun yi »
- Mirza seto apeje latifio gbalejo olumojuto ile owo ati oro aje ilu
Punjab.
-
Iku Mirza : Lojiji ni Mirza safenufa arun Cholera funrare. Abamo ati
itiju lo fi so edun okan re ikelin fu
baba iyawo re wipe :
« Mir Sahib !
« Mo fi enu ara mi fa arun ajakale
Cholera » ko le so gbolohun kankan
mo ti iku fi mu-u
lo.
- Mohammadi
Begum gbe igbesi aiye irorun ati orire fun odun marun le
logbon lehin iku Mirza
Ghulam.
- Molvi
Samaullah Amratsari, semi pelu irorun ati orire fun ogoji odun
lehun iku Mirza
Ghulam
1908
- Hakeem Nuruddin di arole alakoko
1914
- Hakeem Nuruddin subu lori esin o fi bee ku
- Mirza Basheeruddin Mehmood, omo Mirza Ghulam di arole
keji
Dr Syed Rashid
Ali
P.O Box
11560 Dibba Al Fujairah U.A.E
6
__________________________________________________
Do You Yahoo!?
En
finir avec le spam? Yahoo! Mail vous offre la meilleure protection possible
contre les messages non sollicités
http://mail.yahoo.fr Yahoo! Mail