Bismillah Al-Rehman
Al-Raheem
MUSLIMS ,
PLEASE WAKE UP
AKIYESI PATAKI SI
ABURU TO WA NINU IJO
AHMADIYA TO TOKO
ESIN ISLAM
Eyin omo iya wa ninu esin Islam lokunrin/lobinrin,
Ni nkan ogorun meji o din Ikan seyin ,ni
awon alawo funfun elede geesi (Anglais) wa si ori ile Indian gegebi onisowo
.Won foju si ofin lowo awon musulumi, leyin eleyi awon musulumi doju ogun ko
awon elede geesi leralera .Ninu awon ogun yii,meta je koko pataki ,inu re ni ti
odun 1857 ti ogbeni Syed Ahmed Shaheed ti won fe le segun awon elede Geesi
lorile ede Indian ,afi awon manafiki ninu ijo musulumi .
Latari
ati koju ogun jihad yii ,won gbe awon igbimo oluwadi dide (Anglais) lara won
lati ri awon amofin, awon oniroyin , awon asoju ile ijosin elesin igbagbo ni
odun 1868 lati orile ede [Londres]wa si orile Indian . Leyin odun meji won jabo
fun igbimo asofin .Won tun wa n toro ki won yan enikan bii anabi lati dekun
ogun jihad yi,ni eyi ti yoo mu awon musulumi tele won .
Won yan Mirza Ghulam Ahmad lati fi se ise
yi. Leyin opolopo odun , o kowe si gomina ti Punjab pe oun ni asoju ti igbimo
yan lati dekun ogun jihad . Leyin eleyi , o tun kowe ranse si ayaba ilu oyimbo
[Victoria] Lasiko to n se ayeye odun meedogbon ,o salaye sinu we naa pe baba
oun fun won ni omo ogun odun aadota lati koju awon musulumi lasiko ogun odun
1857 lati fihan pe oun jise naa boti to ati bose ye fun ijoba alawo funfun [Gov
.Anglais] oun si tun te awon iwe pelebe pupo ti oun ha fun awon musulumi lati dekun ogun jihad ,o je pe oun jise
naa ni mimo.
Nisinsinyi ,awon ijo
naa ti wa gbile pupo ti won n gbogun ti awon elesin Islam.
Won n soju aye won foro miran sinu won,
won si n so omiran jade lenu. Awon eeyan kadian naa gbagbo pe awa musulumi o
koju mo esin daada, won si n tera mo ase tinu won daada.
Won je apeere aburu fun esin musulumi
toripe won n fira won pe oga ninu esin musulumi toripe won n fira won pe oga
ninu esin Islam. Won n pe awon ti t ko tele ilana ojise Mirza Ghulam ni alaigbesin tooto tabi ti ko
mesin, won si n fa awon musulumi alaimokan kuro ninu esin Islam tosi inu ina.
Ijo Ahmadiya ninu esin Islam je oselu ati
esin labe nkan ti won fin yan awon musulumi tokan won o ti jinle sinu esin je,
awon bii ti America, Europe ati Africa.
Bakanaa ni won tun n gbiyanju ati koju
awon musulumi larubawa ati ti Bosni kuro ninu ija ti won fee ja (Jihad) Apejuwe
ninu agbegbe Africa in ti won apakan to da ijo Ahmadiya Tariquah sile. Won maa
n dabi shaeton (ESU) ti won n fa awon musulumi ti ko mo nka nidi esin ti won n
sin kuru nidi esin, ki won fi raye gbagbo pe awon ni Ahmadiya.
Bee naa ni won tun fa eeyan to to egberun
lona aadota ni orile ede Mali, egberun merinlelogun ni won tun yi pada lorile,
ede Côte d’Ivoire sinu ijo Ahmadiya.
Lara awon nkan to tun fa itanje, yi ni
owo ati awon nkan elo aye ti ijo Ahmadiya n lo, bakanaa ni won tun n se koriya
nipa fifi obinrin tore fawon to ba gbagbo lokunrin lati fi yi okan awon tokan
won o tii gbile,sinu esin pada.
Awon odo Africa, Europe ati America pelu
awon asatipo (to fi orile ede miran sebugbe nitori ogun) ni won rope ijo musulumi
kan naa ni.
Pelupelu aisi idanileko ninu egbe ile
okeere fa alafo si okan awon musulumi, ati wipe oro awon ojogbon ninu esin lo
mu ki won pada sinu esin Islam.
Gbigboro
esin Islam laarin asiko ranpe ni awon ilu okeere je iyalenu paapa julo fun awon
olori ijoba won (Ilu okeere)
Ijo
Ahmadiya dabi igba ti eeyan mu nkan ogbin onikoro fun iwon ogorun meji odun
(200 ans) seyin, to wa hu irugbin. Eso aburu to wa jade latara ijo Ahmadiya lo
wa da iyapa sinu esin Islam. Ijo Ahmadiya naa wa tara eleyi di esin to gbegba
oroke (atewogba jakejado).
Awon
ijo Ahmadiya maa n ko iwe si ogo fa ede (120) losoosu ti won si ma n pin
kaakiri agbaye. Lowolowo bayi, ile
ise mohun maworan kan ti wa ti won da sile ni Londres ti won si ma n se eto ti
gbogbo agbaye Lanfani ati maa wo labe ile won, bakanaa ni won tun lo ya ero
igbalode amayederun fun teru – tomo lati maa wo lori moun – maworan (satelite)
ni eyi to si n nawon lowo gidigidi.
Owo
pupo gidigidi ni ijo Ahmadiya n na, sugbon kii nira fun won lati ri toripe awon
ogunna – gbongbo ninu ijo yi to lowo lowo ma n tiwon leyin.
Eni
kookan ninu awon olowo ijo Ahmadiyya yi na n fi ida mefa si ogbon ninu ogorun
(6-30 %) owo won toro lati fi ran awon asoju won lo kaakiri agbaye lati lee lo
ma fi yi okan awon musulumi pada, sugbon eleyi ko je nkankan.
Bakana,
awon elesin igbagbo ati awon omo ile JUU pelu atileyin ijoba won. Fun apeere ni
odun 1989, awon ijo onigbagbo ti Ethiopie na owo to to $ 35 million lati fi te
iwe ilewo Ahmadiyya lofe kaakiri ile iwo oorun Africa. Awon apejo awon onisowo
tile JUIVE tun fi ero itewe – jade (Imprimerie) toro fun olori ijo Ahmadiyya
(Mirza Tahir) lojo to n se ayeye ojo ibi re.
Eyin
omo iya wa ninu esin Islam lokunrin, lobinrin e ran wa lowo lati ta okan awon
elesin Islam ti aburu inu ijo Ahmadiyya ti ko lese ji pada sinu Islam.
A n te iwe jade lorisirisi ede ta
si n pin lofe fun gbogbo agbaye.
E ranwa lowo lati se awon nkan wonyi.
-
E ba wa tumo awon iwe to tako Ahmadiya
-
E ba wa te awon iwe wonyi jade
-
E ba wa pin awon iwe wonyi kaakiri agbegbe yin.
E dara po mo
ijo to n gbogun ti Ahmadiya.
Tife tife lati
owo omo yin ninu esin Islam.
Dr. Syed Rashid Ali
P.O.
Box 11560 Dibba – Al Fujairah
Emirats Arabes
Unis Fax 971.92442846
E-mail :
rasyed@emirates.net.ae